A MOJUBA SI NKA TI AN PE NI WEB 3.0

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
3 min readAug 11, 2021

--

Web 3.o je nka ti an pe ni internet service ti generation o ni pele meta, o je open web ti awon developers ko si ori open source software. O gba wan ni bi odun mewa ki won to le move lati web 1 si web 2 ati web 3.

Web 3.0 je decentralized ati infrastructure ti o n gba ipo web 2 ti o wa centralized. Web 3 o wa centralized ko de dale ori middle man kankan, bi o shey n gba ipo ori e fun lilo ni ojo iwaju, web 3 gba ni lati ni data ownership, idabobo ati lati le mu ojo to.

A tun le pe Web 3.0 ni semantic web to n mu new era wa ti o si n gba ipo ojo ola open wen si owo.

E je ka mu apeere web 2.0 ati web 3.0

Web 2.0 je open web to n lo uber app lati fi le wo location ati goggle app fi wa motor.

Wen 3.0 apple siri ti o n lo owun lati fi gba instructions ati feedback.

Web yi n lo artificial intelligence ati 3D image fi produce brilliant ati web to wa advance fun applications ati websites.

NEAR ni kan ni blockchain to ti advance tosi ti develop lati lo ero eto open web

ANFANNI LILO WEB 3.0

• ero web search ati ipo to gara ti o je ko wa ni iranrun fun lilo.

• idabobo data

• idabobo ati iranrun to wa fun lilo fun elomiran.

• si san owo ori kekere ni igbati kosi eni keta ti oyinbo pe ni middleman ati central authority.

• ni ayini Idina lati owo thirdparty (ads).

• a le shey eto internet ti a ba fe lo fun rara wa.

LATI MA LO DECENTRALIZED MEDIA PELU NEAR LORI SOCIAL MEDIA

Social media ti wa centralized ni ojo to ti pe ti o si ti n change pelu ero blockchain to ti igba igboro, decentralized to n gba ijoba bi a ti ni decentralized app, decentralized finance ati decentralized exchange.

A ti ko Decentralized exchange si ori social media bi a de shey mo po ko wa ni owo enikankan tabi organisation kankan. A ko data kakiri nodes lori social media ka lori agbaye ti information ori e si wan encrypted.

Near protocol wa decentralized, o ma n store data o si fi awon users e ni anfanni lati wa ni control data won.

Centralized protocols bi a she ri ni oririsiri iyonu bi ki won ma ta dara fun awon oni showo oja won si ma n lo fun ise ose ilu, centralized media tun ma n lo lati fi le ma market oja ni ayimo fun onlo. To ri e ni decentralized sexual media app shey je ona abayo.

Ero Decentralized social media app tin ma ode bi decentralized social media app je ona ti awon technology tuntun lo fun eto won.

Pelu kiko ero decentralized media si ori NEAR ale integrate NEAR wallet ni ona ti awon elo le fi transfer near token won si awon ara ati ore ati melebi won ni iranrun.

A le ri awon idoju ko kan si miran vi

▪︎awon idajuko bi ilana ti awon ijoba la kale fun centralized institution

▪︎bi gba wole ni awujo

Mi ni igbagbo wi n pe awon developers ori NEAR le mu eti decentralized social media app wa si ori NEAR to ri NEAR wa scalable, effective, efficient, climatic neutral o si wa developer friendly.

Won igbinmo NPKGUILD(Nearprotocol) lo ko ile yi

Website: https://near.org/
Twitter: https://twitter.com/NearprotocolNG
Telegram Official Channel: https://t.me/cryptonear
Telegram Nigeria Community Chat: https://t.me/NPKGUILD

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet