AWON NKAN TI E NI LATI MO LORI ETO NEAR USDT TI O NBO WA SI ORI ETO AURORA ATI BIRIGI OSUMARE

--

Awon orisirisi nkan lowa ni ori Aurora ati NEAR ti won tu n ti birigi si ori Ethereum awon USDT ti o jo ara won ni won maji papo si ori birigi osumare lati ori USDT ati NEAR.

Opolopo awon nkan ni o ti wu ro ninu Aurora, pelu idi eyi Aurora ti jeki awon nkan miran wa si oru birigi bi lati so USDT si USDT.e ni eyi ti Aurora ati NEAR ma je ki o di nkan ara lati ojo Friday ti osun September oji merindilogun ni odun 2022.

Ijora USDT.e ni a ma gba ni iyanju lati ma lo yato si ti USDT ti won birigi si ori osumare tele. Ko si nkan to ma yato ti won ba so ijora na si USDT.e ti owo ni ori Ethereum. Ko ni si iyato nini contract ti o wa ni ori e tele ati pe metadata ti o wa ni ori eto na tele ko ni ni iyato pelu AMM pool ti o wa ni ori birigi USDT.

Lori Eto Ti O Fe Waye Ni Ori Birigi, E Yi Tun Mo Si Win Pe:

Eyan le birigi Aurora USTD.e si ori Ethereum lati gba USDT lori Ethereum (yala ki oje USDT (Ethereum) ti won ti Birigi si ori Ethereum si Aurora ki a to gba update na wa si ori ila).

Eyan le birigi Aurua USDT si ti NEAD lati gba USDT.e ati ki eyan birigi NEAR USDT. E si Aurora lati gba USDT.e

Eyan le birufu NEAR USDT.e si Ethereum lati gba USDT lori Ethereum

E mo win pe:

“USDT” loru NEAR ati Aurora ti gba ti eto NEAR-native ti tokini USDT

Awon Eto To N Bo Wa Si Ori NEAR USDT Ma Gba Isora Si Ori NEAR

NEAR-native USDT ko le je birigi si ori biriji osumare si ori Ethereum, eyan ma ni lati yi pada si USDT.e na ki won to birigi e si USDT.e Ethereum.

A ma reti ti NEAR ati Aurora mu pool USDt.e ati USDT ti o wa ni ori Aurora ati NEAR si ti USDT ti wo n to depoly e. E ma ni iyanju lati reti eyi loti Trisolaris (https://trisolaris.io/#swap) ati Ref Finance (https://app.ref.finance/). Ko ni si agidi fun awon Dex to lu lati gba iyanju.

Iwe Si Awon Dev Ti Won Ko Ero Aurora Ati NEAR

A gba awon dev won yi ki won ke ji awon nka ti won n ba n ko ma ni iwulo lori awon eto wonyi lati ma gba won ni iyanju lati ma je ki awon nkan ti wo n shey ma ni iwulo si awon eyan loru metadata tabi lati ma gba repos won loru metadata (bi apeere lori isanwo token) ni ori eto to ba yato, projecti ati ipawo si gbodo wa ni update lati ba ilana to wa ni ori USDT.e lo.

For more information, visit

Website: https://aurora.dev/blog/aurora-launches-its-validator-on-the-near-blockchain

Twitter:https://twitter.com/auroranigeria_?s=21

Telegram: https://t.me/AuroraNigeria

https://aurora.dev/blog/native-usdt-on-near-and-its-implications-on-the-rainbow-bridge-aurora

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet