Awonran ti o sheyle ni inu odun NEARCON
NEARCON 2022 ni igbalode ni ilu Lisbon ti awon eyan NEAR ti fi arayo pelu asa ati irawo NEAR ti gbogbo ilu kan pelu awon eyan to n l bi ogun ti awon wa fun eto na. Odun era ni fun NEAR protocol ti awon diran fun ni opolopo, orisirisi awon eyan lo wa ba won she ajoyo yi ti awon miran si ri nkan to dara mu bo ni be. Orisirisi ounje ati ere igbalode ni o sheyo ni ibi ayeye na, awon olori project ati hackathon.
E je ka wo awon nkan ti o ti di owun ara ni inu eto NEAR lori NEARCON.
Awon opolopo awun ara imunu do ma gbere si ni jade lori ero eto NEARCON, ki o fi ojusile fun awon iroyin na.
NEAR fe da eto ise fun ara ilu le lori ijoba ecosystem won ti on je NDC
Inu awon amojuto NEAR dun pupo pelu eto ara otun ti won mu wa si ori eto fun awom ara ilu ti won no eto NEAR ni peyewu ti won fe da eto ti an pe ni NDC, ti o tin gba ara otun yo ni ori eto lati mu ilosiwaju fun Web3 ati awon ecosystem to jo sowope.
Eto sustananci Ka ki ogba owo lori e pelu “Coinbase Earn”
Pelu wi wa pelu eto to ni agbara ju, ti awon eto ori e bi owo ori kekere, ero a yara ni asa ati awon nka to dara. NEAR darapo mo ikan lara eto to ni gbajumo ni awujo ti an pe ni coinbase lori eto Coinbase Earn lati je ki awon onlo NEAR ni imo ati iwulo NEAR eyi ti ilowe Web3
Awon obirin ti o di ipo Web3 mu
NEAR foundationu dara po mo Forkast lari gbe asa awon obirin inu web3 si oke ati losi iwaju, inu NEAR dun lati gbe eto Web3 soke ati lati wu oju awon to jaweori bori ni inu eto Web3 changer ti awon obirin.
Ni inu awon ibo bi Ogun ogbon 1,167 ti awon bi Ogun mejo 180 ni awon dibofun ti awon ni mejila 11 jawe olubori ti awon be Mewa 10 jo ni ipo kona ti a me fun won ni ebun ni ojo NEARCON.
Oruko ati ipowo ni iwuni ni isale ni sheye n tele.
Amy Soon, oludari Blu3 DAO
Bianca Lopes, osise Advocate ati owo igbin
Deborh Ojengbede, CEO fun Blockchain AFEN
Erukan Obotetukudo, oludari ati partina fun Audacity
Lauren Ingram, oluadri awon obirin inu Web3
Medha Parlikar, ibimo oludaru Casperlabs
Oluchi Enebeli, obirin akoko blockchain engineer ti oda Web3ladues sile
Sian Morson, oluadri ati oluko fun TheBlkChain
Wendy Diamond, Web3 impact Investor, LDP Ventures, CEO/oludari Ojo ise fun awon Obirin ti oyinbo n prnu Women Entrepreneurship Dat Organisation (WEDO)#ChooseWOMEN
CEO fun NEAR Foundation Marieke Flament so win pe “ni apapo a le jo shey nka meremere ati lati ko awon iwe eri to dara ati lati lowo pe kakiri aye.”
Tether ri ile tuntun ni inu NEAR
Inu NEAR Foundation dun lati dara po mo Tether (USDT) eyi ti o ma mu ero igbalode wa si ori NEAR ati lori ecosystem Defi.
Eto NEAR Foundation tun bo so awon orisirisi partnership to wole wa fun eto ecosystem NEAR NFT
Eto Nightshade sharding Phase akoko ti gba ilu
Ni oju akoko NEARCON, awon opolopo iroyin lo wa lati ori Nightshade Sharding ti eto Pagoda ti Web3 ati eto funNEAR Protocol so launch Sharding Phase akoko ti o wa ni dasile fun gbogbo awon nkan tecnical ati lati je ki awon Validator increase lati le mu eto na jade sita.
Pogada so win pe eto yi ma wa no iduro ni odun 2023.
NEAR ati Caerus sowope lati shey irinle eto owo fun awon to ma n create nkan
Eto NEAR Foundation na ni iroyin imunu dun fun awon iluya. Pelu imulowo pe pelu Caerus ati owo bi Ogun million $100M ma je ki awon inkan lo ni irawo irorun fun awon generation to ba n bo.
E fi ojun finle fun opolopo eto to n bo wa ni ojo iwaju.
Oluko ati Otu si Yoruba
For more information follow us at;
Twitter : https://twitter.com/nearprotocolng?s=21
Telegram: https://t.me/NPKGUILD
Website: https://nearnigeria.org/