BI A SHELE DIN ERO ORI NEAR ECOSYSTEM
Opolopo awon eyan lori bi yield farming, Defi ati NFT ti shey gba igboro ti awon elo wan yi si n da lori ero Ethereum tabi Binace blockchain. Opo awon Africa papajulo awon Nigerians ni won je anfani ero ti ecosystem gbekale. Pelu owo ori Ethereum bo shey po to ati awon orisirisi ti an gbo lori ijamba to n shele lori BSC, opolopo lo wa ona abayo pelu bi ero eto blockchain mejeji shey n losi ati ni ojo iwaju.
Eto NEAR je ero to wa decentralized, ti o si gbe ona lori eto to wa decentralized, o je eto to dara to awon developers na si n ko ise won le lori to awon blockchain miran si n gba wole, ko ni ni lara owo ori re si shepere ti o yara bi asa, ti o si n mu developers shey ise lori e ni iran run.
BI NEAR PROTOCOL SHEY WAYE.
Awon igbinmo eyan ti won ko ara won po ti won ko ero eto NEAR protocol ni an peni NEAR COLLECTIVES. Awon won yi ni kan ko lo da eto NEAR sile awon miran bi researchers, developers ati awon to ma n ro ori wan. Awon ti o je agba ti won da eto NEAR PROTOCOL gangan sile ni Alexander skidavor ati illia polosukhin. Awon igbinmo yi no wan da ero NEAR protocol code sile pelu innkan ti an pe ni Bug fixers, update ati kilo ile eto ero NEAR protocol sile.
BI NEAR PROTOCOL SHEY N SHE ISE.
Irawo to wa ni eyin eto NEAR protocol operating system ni an peni Nightshade ati Doomslug mechanism.
• NIGHTSHADE: Nightshade je oka n la ra sharding system to ma n ya aworan snapshot shard kankan ti o si ma n add e po mo block, pelu sharding kankan to ni validator notes won ti o ma n so ipo ti shard kankan wa ni igbakigba ti block kan bi ti waye.
• DOOMSLUG: Doomslug je ero to ma n jeki validator notes gba block kankan ati ki block tuntun ma generate ni isheju kankan eleyi wa leyin NEAR PROTOCOL ecosystem.
EYI TO TELE NI NEAR ECOSYSTEM
Ni ayifiso orisirisi bi dapps 50 lowa ni ori NEAR pelu FLUX, MINTBASE, ati PARAS ti o je eyi towa ni asikoyi, o dalori dapps ti awon developers ati awon eyan nlo, ti a ma fi n store data, stake tabi ti a ma n fi shey awon ise miran lori NEAR protocol token ti an pe ni NEAR token. Ecosystem yi je non server ti o wa ni iwulo lopolopo o he blockchain ti gbogbo eyan le ni assess si.
DAPPARADA ti pada gba NEAR protocol si inu service won ti on lo bi dapps mejo lati ori NEAR protocol token incorporate won . dapparada je platform ti o ma n keep track decentralized apps ti o de ma n jeki awon elo won lo pelu iranrun, iru eleyi je ero gidi fun awon ti wo n lo NEAR protocol ecosystem.
Awon eto ti mo ma ka le yi ni dapparada ma n fi keep track awon ero won.
1. Nearpixel
2. Near names
3. Ref finance
4. Rainbow bridge
5. Benyclub
6. Sputruk DAO
7. Paras
8.flux
9. Pulse
NEAR PROTOCOL TOKEN $NEAR
Near protocol token je NEAR currency ti NEAR protocol ecosystem ti a ma n lo gegebi unit value fun transaction. O ma n je ki awon ti won ni NEAR token lati lo orisirisi application lori near, lati ma shey network governance ati lati ma stake token won si ori network.
Awon ti won ma n lo NEAR tokens ni mo ma ka si isale yi
• AWON TI WO N MA N LO NEAR: A ma n fi NEAR token san owo lori NEAR ecosystem fun awon orisirisi nkan.
• VALIDATORS ATI DELEGATORS: Awon token holders ni aye lati stake token won won de ni anfani ati ya token meta si ori validator pool ti eleyi yi si ma n fun won ni ebun . Awon nodes ti won ma n shey ise ti lori network ma n gba ebun lori awon staking yi.
NEAR PROTOCOL SI NIGERIA
Nigeria jejebi developing country ti won gbiyanju lati ma lo decentralized app, near protocol je ona ti a lelo gba fun solution lati fi boost economic crisis ni Nigeria.
Awon onka i le yi ni ona ti Nigeria lefi je anfani lati ara near protocol
1. Afanni fun awon nigerian ni dapps je ko ni eyan lara o si gbe owo peli, re dapps gba Nigerian ni iyan lilo e ni ori ero orisirisi bi trading dapps, supports dapps, exchange dapps to ma la ona fun awon Nigerian kekere ti won bo leyin.
2. Lilo fun orisirisi business, a le lo NEAR protocol lati fi le jeki business wa wa ni ipo to da ati ni idabobo, a le lo draft policy to wa ni ori business na ni eyi ti eni to ni business ti ko tele pelu NEAR lati fi dabobo business na.
3. Lati fi gba token NEAR protocol, Nigerian le shey Near bounties, lati participate ninu ka ma run community businesses lati ma n jeki awon eyan build lori NEAR lati le gba near token.
4. Lati ma lo dapps, orisirisi decentralized app la ni lori NEAR protocol, eleyi de ti shey anfani fun awon entrepreneurs lati lo NEAR ni ona meta
Games dapps ti awon game centres ma n lo, trading dapps ti awon onishiwo oja ma n lo atibebelo, eleyi je ona pataki ti awon Nigerians lo lati le fi explore orisirisi blockchain papa julo bi ETH ati BSC ti o je ona ti elo dapps adot lati le fi lo NEAR ti o si mu igba otun wa pelu lilo re.
Ni akojopo
Lilo NEAR protocol ti mu igba otun wa fun awon ti won lo blockchain tele, ti o to gbani ni iyanju ati anfani lati le lo platform to dara lati fi shey transactionu nla ti ko ni ni lara pelu owo kekere lori e, ti o si je igba otun fun ero igbalode to awa ni inu re yi.
Website: https://near.org/
Twitter: https://twitter.com/NearprotocolNG
Telegram Official Channel: https://t.me/cryptonear
Telegram Nigeria Community Chat: https://t.me/NPKGUILD