BitGo Je Ero Apeleko Akoko Lati Gbe Eto Weo NEAR Protocol Soke Ninu Wujo

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
3 min readJul 26, 2022

--

Inu eto ero Near dun lati ba Near Foundation dowo po ti won si kede ajoshey to wa ni arin owun ati Bitgo, eyi to je oga akoko nninu eto oro aje ati akoko ti o yeye ni inu eto ishora ati abo ero Near protocol. Eto isowo wo yi ma fun awon eya ara imo oke ni eka institution igba lode pelu eto ero ishowo lati ma lo Bitgo fun eto ero aje won lori ero to gbona to si ni idabobo to dara. Awon onlo Bitgo ma ni anfani lati gbe owo won lori eya staki to wa ni ori Bitgo lati le ma gba ilopo lori owo na lori wolleti Bitgo.

Inu Bitgo dun lati je akoko eto lati mu imulowo wa fun ero eto NEAR Protocol pelu awon eli Near protocol ti won ti n wa anfani lati fun eto ero wan pamo ati lati le staki owo wo si ori ero na ti a gba oro eleyi wa lati enu Mike Belshe eyi to je oga Bitgo CEO. O tun ni inu wa dun pupo lati gbe eto ti kale fun awon eyan lati le fi owo won pamo si ori ati lati le staki eto Near won ni irorun lati si shugbon tabi kankan ni nu e. Bitgo tun gbe ara oto ja de pelu eto iso yi, ni eyi ti fun NEAR Foundation ni eto lati le je idabobo ni ori Open Web.

Ni owolowo yi Bitgo je oga ninu eto on-chain Bitcoin ti won shey eya gbigbin Bitcoin bi pectin Mejila ni Kaka ki ri agbaye pelu bi egberun marun token ti NEAR tokini Hershey dara po mo won. Eto NEAR protocol ni igbagbo pupo ninu Bitgo ti o wun ni anfani lati le wo inu ecosystem wan lo lati gba eya awon eto oro aje won lati ma lo Bitgo fun isho owo wan.

Gbogbo awon eto oro aje Bitgo kaka kiri agbaye papa awon oni ero cryptocurrency ni gbogbo agbaye ati awon oni ero bi egberun mega ju belo. Ti awon eto oro aje bi Goldman Sachs, Craft Ventures, Digital Currency Group, DRW, Galaxy Digital Ventures, Redpoint Ventures ati Valor Equity Partners ti Bitgo je oga ni inu eto ero igbalode ti won pese iso, idawo, idabobo, ati eto liquidity fun awon era won.

Ero NEAR Foundation CEO ti on je Mariele Flament ri isowo Bitgo bi anfani ati mu ero eto NEAR Foundation ati awon won ninu ecosystem won ati lati ni eto diverse community fun awon eyan ti won ko eto ero NEAR Protocol.

Eleyi ma fun awon eto NEAR ninu eto gbogbo ero agbaye, Flament tun so win pe pelu eto ero Bitgo, a ma fun awon eto ilo Bitga ni iso to peye ati anfani fun awon ti won lo Bitgo. Pelu won a ma ni awon ero to po lori ecosystem wa ati gbogbo web3 eto igbalode ti a wa yi.

Ni Odin 2020, Bitgo ko eto Prime Trading ati Lending ni imo pelu Bitgo Portfolio ati Tax ti won fun awon eyan ni full stack ati eto igbalode. Ni 2018, Bitgo launch awon Trust Company ati eto ero digital assets, ti won mu ishey won ni okunkun dun ni odun 2013 be si ni ninu NEAR ni ojo to ti pe.

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet