E Darapo Mo Stake Wars Lati Ti Ara Awon Oludasile Won
Stake wars ti de lati ba awon eyan shey eto ero NEAR wo ati lati ba awon ara ilu pelu eto tuntun to ni ebun ninu fun awon onlo won ti won fe darapo mo awon validator lori NEAR. Ni ipinle keta lori Skate Wars, NEAR fe koju si eto ti awon elede oyinbo n pe ni Chunk Only Producers — eyi to je igbese to kan ninu eto NEAR ti an pe ni sharded protocol.
Pelu bi won shey gbe eto ti an be ni Validator kale yi, won ma ni lati increasi awon eto validator won ni a papo. Anfani yi ni lati fi le ni okan pelu awon Chunk Only Producer ti ini Stake Wars ati lati fi le shey ise ti an peni delegation. Pelu eto ero Stake Wars ti on be wa si ori ila ni July 13, awon ilana to ma mu enuba yi lori Chunk-Only producer ti ori ila eto Stake Wars.
Awon Chunk-Only producer Ma Ba NEAR Gbero Decentralize
Awon eto NEAR network wa ni isho igba validator. Eto ona Near ma jeki o wa ni eto fukly-sharded ti o a jeki e mo e wasi mumushey lori eto isho validator ti ori Chunk-Only producer ti ilana to wa ni ilana to peye.
Awon Chunk-Only producer ni won ma n ni anfani lati shey eto idasile Chunk ni inu shard kan ti an pe ni (Network partition). Nkan ti o ti je owun ara lori Chunk-Only producer ni pe won ma n shey ise lori machini ti on lo bi 4-core CPU pelu RAM 8GB ati SSD 200GB lori ile ifipamo.
Ti eto Chunk-Only producer bati wa lori mainnet NEAR ni ipari Q3, NEAR ni eto lati fi gba awon validator bi ogorun meji ati ogorun meta (200–300) pelu ilana kekere ti oyinbo n peni (minimum stake) fun awon validator, eto yi ma mu awon eyan wa si ori ero NEAR ati pe awon oro validator won ma gbero si.
Bi Eto Stake War Ipinle meta III Shey Ma N Shey Ise
Chunk-Only producer ni eto lori si eto stake pool smart contract lori Github lati le fi shey idanwo fun awon system ati lati fi ni igboya lori base contract delegator ni ede oyinbo. Validator ni anfani lati da customize delegation contract ti won sile pelu lati ko eto ero ati integrate staking pool won sinu eto to wa nile.
Stake wars je eya community operated pelu awon eya community members bi Metapool, Everstake, Linear ati Open Shars Alliance (OSA) ti won ni iranlowo fun eto na. NEAR ni eto lati bi 4M $NEAR token fun awon delegation lati le darapo mo awon to ma shey igbaradi na. Awon even yi ni lati fi jeki awon eyan darapo mo awon to le di validator lori mainnet ni Q4 2022.
Testnet fun Chunk-Only producer lori Stake Wars ni ipele III to a launch mi July 13 to de ma wa ni eto di ibere osu September. Awon ti won ba fe darapo mo awon Stake Wars Community le lo si ori Telegram ati Discord won lati le darapo mo awon validator mi ran ati @PagodaPlatfotm fun Twitter won.
Eto Stake War ipele III ma wa ni idasile ni ojo to ko pe mo.