Eto Granti Lori Ero Gitcoin Ipinle Kedogun A Bere ni Peyewu Ni Osu Sept 7 Odun 2022

--

Inu wa dun pupo lati so fun eyin eyan winpe Gitcions gba ipi eto ebi igba ipile 15 ti owo ni arin ona! Eyi to ma bere ni Osun Sept 7 titi wo Osu sept 22 inu odun ti a wa yi.

Eto ecosystem AURORA ni won da eto yi sile lati gba awon eyan ni iyan ju lati ko ile si ori eto AURORA peul ebun ogorun dolla ( $100 000 ) ti o ma jade mi ori owo AURORA.

Won gna awon ti won ba fe pese eto projecti won ki won tete te ran shey ki eto grant na to bere ni peyewu ti o ma fun won ni anfaani ti grant won le ni itewo gba, tori awon oga to wa ni idi eto na ma fun bi ojo meji si meta lati le wo eto projecti na pelu suru ki o fe le ni itewo gba.

Eto yi ma bere ni ori gitcion.co/grants ti o si wa fun gbogbo awon eyan ti o le shey ise eto na ni daadaa pelu iranrun ti awon imulo won ma lo bi:

AURORA di ipo to gbajumo dani ti awon garanti le duro lelori, awon projecti ti awon eyan ba san ma koko koja ni ori eto GitcoinDAO ti o shele fun gbogbo eyan fun lati fi dipo lori projecti to ba jawe elubori.

Awon ipo pataki pataki ti o romo eto na ni yi ni isale:

1. Eto granti na gbodo ni idojuko lori ilana tabi ise eto ecosystem AURORA.

2. Eto granti na ko gbodo ni ifinle lori eto owo ( bi ki awon elo ma fefi ogbon gba owo tabi ebun ni ilano ti ko peye).

3. Eni to ba ni eto granti na ni ki o dojuko, ki oni to wun si lo granti na fun nnkan ti o ba sope o fe fi shey ni ori ilana to granti no bawa.

4. Eto granti na gbodo wa lati le tele ilana ti AURORA gba tan kale bi awon won yi:

· Eto lilo — Eto granti na gbodo wa lati le mu ilo awon eyan ni iduro

· Awon ero — Eto na gbodo wa lati le ma fun mu ecosystem na lo si iwaju

· Irinshey — Ogbodo wa lati le ma eto developer losi iwaju

· Ijoba — Lati le ma gba eto ijoba ni idanrun

· Oshelu eto — Lati le ma shey isora fun awon ijoba ati omo leyin ijoba

5. Eto granti na ma je eyi to le diramum

6. Projecti na gbodo wa ni ilana eto ati ise ecosystem AURORA

7. Eto granti ti won file leyin eto na koni ni itewo gba

Ati shey to igbe se lati gbere ilana eto na

· E ma losi ori ero Gitcoin lati bere granti na ( https://gitcoin.co/grants/new )

· E tewo ba awon inkan to ba je koko ati tagi to ba ilana eto granti yi n lo ( e gbodo mu tagi ero AURORA ki eto yin le ni itewo gba).

· Eto granti na le wa ni ilopo si ki e ri wi pe e tagi gbogbo inaka to ba gba ilana na lo.

· Eto granti yen ni lati wa no itewo bo ( lati wa ni ori ero Gitcoin ) to ri tagi awon ra yen ma wa ni yi yo ti eto granti na ko ba ba ilana ti a la sile ni oko yi lo

Ki lo tun kann?

Oya ema ba eto lo

Agba iyanju ni wa lati owo olutu si ede Yoruba ti oruko e n je Omidan Ruqqayah Shofela olutu si Yoruba fun NEAR protocol Nigiria.

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet