ETO IDABOBO LORI NEAR WALLETI TI WEB 3 TI IFI OWO PAMO
Ni tori gbogbo yo go diyan ton lo pelu bi awon eyan shey n tampa pelu iso lori awon wallet ti on lo ni awujo lori web3, ni to ri idi eyi i a shey fe tan imole si nkan ti o wa ni ori eto Near.
Ni ofun 2022 ni osu June ojo kefa, awon iso idabobo lori Near gba ipe loti ero wan ti awon adani loro yi fe fi shey jamba fun won ni ori eto won ti o mu ki awon eto idabobo yi gbe igbimo ki awon eyan ma lo Email ati SMS mo fi gba eto na ti ikan ninu awon olushey Near ti on je @Hacxyk ri eleyi ti won si fi gbogbo ikalo sile fun awon olushey lori eto na ni osu June ijo kefa ninu odun 2022 ti won si ti gba ebun lori eto yi to ri pe ko wo po larin awon eyan lati ma shey iru ishey ti ogbeni hacxy yi shey fun eto Near.
Awon oludari eto na tete gbe ighese lori eto yi won tete pa ina lati wa eni to shey iru ise wonyi ati bi o shey ri anfanni si awon apele ko to wa ni ori ero na.
Titi di waka ti yi a o ri nkan kan to jo mo ijamba lori eto wa be a o ri eyan kan kan ton gbe igbese na sugbon ati dekun lilo ero email ati ti ero sms lati ma fi gba nkan ti an pe ni codi ti eyan ba fe lo ero Near, yala pe a o ri nkan kan a shi tesi wanju lati dekun lilo ero email ati SMS to ri a ni igbagbo win pe awon eyan leti fi eka yi shey janba ti o si le je nka fun wa ni ojo iwaju. Ti awon eyan lelo ti won ba losi ori ero lati te MyNearWallet ni ede gbesi ti won le pa ina irufe eto yi lori eka Ledger ( eyi to ni idabobo ju lo ti a si gba ni imoran fun gbobbo eyan) tabi nkan ti an pe ni passpharse idabobo leyin eyi ki awon e ro pa ina eka email ati sms.
Pelu iranlowo eto open source ti ori near lori My Near Wallet awon orisirisi nkan lon le ni isale. Agba awon onlo wa ni iyanju lati shey idaabobo fun ero wan ati lati moju to bi eyan shey ma le fi idinwo lori eka won lori lilo Ledger tabi eka to gbono dokun ati fifi wallet wa n si ori ero ti koni ko jamba bawon.
Eleka eto idabobo yi lori My Near Wallet ti lori blog wa ni eka medium lati ka ede meta to wa bi ori le ede Nigiria ati bebelo.
For more information visit
Web site: https://nearnigeria.org
Twitter: https://twitter.com/nearprotocolng?s=21
Telegram: https://t.me/NPKGUILD