FI FI OJU AFRICA WO IWULO DAPPS TI O WA NI ORI ERO NEAR PROTOCOL

--

Imuni wo si ero dapps

Kini an peni dapps(application to wa decentralized):

Dapp je ero lori computer systemu ton she ise ero lori computer systemu. Awon ero pupo lowa ni ori dapps ni ero bi Ethereum blochblockchain, ti a pe aponle e ni smart chain.

Dapps shey ise lori ero computer to si ma n lo innkan ti an pe ni code work lati fi le shey awon ishey decentralized app lori ero peer to peer ju awon ti code wan ma n shey ise lori centralized app lason. A le fi awon dapps wa pamo lori awon ero bi swaps tabi ipfs, ti awon fronted codu won wa ni inu interface ti a ti ko si ede ti computer mo.

Ni apapo, awon Apps ti owa ni ori distribution computing system awon bi Ethereum tahbi bitcoin ati decentralized applications ti wan fipama ati execute pelu blockchain system .

Awon apejuwe app tiwan wan funwa re ni abeh re ati awan diagram:

_Blockstack _ awon platform tiwan fin developed decentralized application .

_Augur(10) isohrah fun oja platform

_Cryptokitties _ ere toni latishe pelu Ethereum . O slow Ethereum sile tori ko si sufficient transaction processing ati exposing osunwan limitations ti public blockchain.

_freelance _ platform ni ori smart contract .

Diagram ti oma towa si ona Dapp ati bi oshe function

A o le fi oju fo iwulo dapps tori wan ko si ori ero p2p to shey ishey operating systemu. Dapps da ecosystemu to dara sile to si wa ni idabobo, ti o si fun awon developersi ni anfani ati shey irin ishey tuntun ti o po ti shey dada ni awujo

Ojo ola Dapps

Shey o fe mo nipa ojo ola Dapps ni odun yi? Imo nope blockchain yi wa ni idara, nipa Ika ati iyawo ti awon blockchainu shey, Dapps yi de be egberun 21,027.2 USD ni igbeyin osun 2025.

Dapps ma ma gbero sode lo ni ojo ola, yato si win pe igbapada yi lema sheyle ni isin yi. o ye ki 2020 mu igbinmo to dara wa si fi de blockchain ati awon ero to wa ni ero e.

Lati mo nipa Dapps, e losi;

https://en.m.wikipedia.org/wiki/Decentralized_application

Mimo ni pa Near protocol

Kini an pe ni Near protocol?

Near protocol je decentralized app ti ati designi lati gba limitation to ma pari system bi ki transactionu low tabi ki speed e low tabi ki o ni crossing ti ko dara.

Awon oludasile near ni ALEXANDER SKIDANOV ati ILLIA Polosukh. Near je blockchain ti o n lo smart contract chain, ti o he community based ti o si wa developer friendly. Awon oludasile NEAR da NEAR sile ni odun 2018. Lati onka lori ero websiti won, a ri win pe eyan le ko app lori ero won ni isheyju marun. NEAR shey eto community-base pelu serverless compoter pelu okan ati wa aluyo si eto ijamba ti an fi oju ki ni isin. Ero near si tun wa fun lati fi awon nkan pamosi, bi apeere NFT ti a ko si ori ero near. Lati mo nipa near e losi ori ero yi. https://dappradar.com/blog/what-is-near-a-simple-explanation

Reef finance ti a ko si ori protocol

Reef finance he rero to a ko si ori near, o wa ni iranrun no lolo. O je ero ti o wa decentralized lati ya nka lori e, ti a le fi isu defi to wa synchronised.

Ref ma gba ipo near lori owo ero transactionu to kere ($0.005) per swap bi iju kan ni apapo pelu ero assembly bridge (hello, rust smarts contract) lati mu ija CEX ati speedi kuro pelu awon multi chain defi ecosystem.

Lilo rainbow bridge tuntun ti o wa ni ori near (Near ☆ Eth) opo eyan lole lo lati fi le shey ero dollars wan ni ERC-20 assets lati ori Ethereum ati lati ori ero mi ran (BSC, Polygan/matics Combos/IBC ati bebelo lori near). E lo si ori ero yi lati mo ni pa Bridge finance si https://awesomenear.com/ref-finance/

Ati pe e le losi ori ero yi lati le ra tabi gba Digital Arts Cards ti o ba wun yin lori paras https://awesomenear.com/paras/

Lati transfer NEAR ati Ethereum lati ori Rainbow Bridge

Ki ni an pe ni rainbow bridge?

Rainbow bridge ma n gba ni la ye lati transifa Ethereum ati won asseti miran lori near- eyi ti network e gbera o si gba ni laye ati sendi assesti won lori near.

Rainbow bridge yi je okan ninu ero ti o shey gbe okan le, o gba eto ERC-20 osi tun wa decentralized, o si wa ni finifini fun lilo ni ojo iwaju.

Lati tesuwaju lori bi eyan shey le transfer tokeni larin Ethereum ati near lori rainbow bridge e lo si ori eka yi https://awesomenear.com/rainbow-bridge/

Ni Ipari:

Dapprader: dapprader ti fi anfani lati fi gba near protocol is ori ero e. Aleju ti wa ni anfani lati ni imo dada ni pa near blockchain. Ati pe dapps mejo ti wa ninu ero ti wan si ma ma fikun ni osu, ose ati odun titi di ojo iwaju.

Oluwo, bi dapprader shey ni iposi ni ori near https://dappradar.com/blog/what-is-near-a-simple-explanation.

FIFI A FI HUN SPUTNIK DAO SI ORI NEAR ECOSYSTEM

E leyi je asiwaju asa nini ero cryptosphere lori onka front ti a ni, o wulo, o dara, o si ni awujo to dara. DAO’S ti an pe ni Decentralized Autonomous Organisation wa ni abe aga community governance, ti ko si ni ni iwulo tobaya lati shey ise ni ojo iwaju lori open source ecosystem.

A le pe Sputnik dao ni Iya dapps lori near protocol, ti awon miran le ma wo Sputnik Dao bi Dao miran, papa o je inka dada ni ojo iwaju fun decentralized governance. Sputnik V1 je ona akoko ti a le gba lo Dao’s. Pelu Sputnik, awon community ma wa ni ori ero dada, won ma na ni ti wan, wan si ma wa ni iranwosopo.

KINI AN OR NI SPUTNIK DAO

Sputnik dao ti launchi community titun, managimenti ati Iranwo tuntun ti ero near ecosystem ati awon guild miran le ko Dao’s ti won ni abe ero Sputnik.

Sputnik Dao je apeere gidi si decentralized ati ara fiddle si ori ero chain governanci fun ori ecosystem. Lori Sputnik, infrastructure nla ti wa ni lati le gba community nla tabi omiwo miran tabi developu timeline miran. Sputnik gba ero gidi lori NEAR ti o gba ni anfani lati ko DAO tiwan lati ori permeates won. Resultant yi wa ni threefold to si dara.

Apeere wi n pe Dao wa decentralized ati ni iwulo.

· Ni a koko, ecosystem ni a papo wa decentralized dada, ati wi n pe DAO’S wa ni arin o

risirisi eka to pi n le lori, ti o ni kaluku si ni ishey ti e ti on shey.

· Ejeki, awon project ti o wan ni ori near ni anfani lati mojuto Dao ti won bi won shey ri. Won le fi awon afin kan si, gbin ona to wo n, won si tun le shey eto token titi won ni iwole gbogbo eleyi wa ni abe Sputnik.

· Eketa, lori ecosystem, fifi owo si ati kiko ero ecosystem ni odindin ti wa ni ipo, tori pe ki a ma pinu tabi send owo o si mo lori Dao kan, opo project le ko ero lori Dao pelu ecosystem to wa ni ori loops won.

Gbogbo ona meta yi, fi won wa wi pe ati ko Dao si ori NEAR lati fi le wa decentralized ati ni imulo.

MESHI DAO

Ogo Dao ni ki o ko mesh-network ti Dao miran si ori NEAR ecosystem, to gbogbo won si ni igbinmo ti won ma fin pinu lori nka. Mo pe, awon igbinmo yi ni ona ti won ma n gba lati shey DAO’S won, ni imo pe won le ni igbinmo wan. Pelu igbinmo yi orisirisi ishey ati anfani lowa lori DAO’S.

APEERE BI DAO SHEY MA N RI

Dao hub shey anfani lati ka nipa anfani to wa ninu Dao. Dao je ibi ti eyan leti fi ibere (payout) tabi bouty (request for work) ti a fin specify ibi ti o wa (set of tags).

Pelu bi opolo Dao shey she ise lati fi owo si inu community ati lati fi ofin si bi awon eyan shey ma ma lo ero na, Dao gbero lati da ise le si ori NEAR. DAO yi ni a ti gbi is inu aworan Sputnik.

Ni ipari, DAO hub ma wa ni inu DAO Sputnik ti o ni ka lu ku ah ise ni larin awon elo wan. O wun ni aponle fun cross chain ati cross protocol ti a ma n ni ojo ola. Iru idarapo yi tun le gbimo ju guild wan lo, si ori ishey mi tabi project miran. Lati ka nipa DAO’S e lo si ori ero yi http://https://www.youtube.com/watch?v=htT1MHzCuEk.

Ti NEAR shi wa ni atibere fun DAO’S, Sputnik he paradigms shifts lori be awon community shey n moju to ara wo lori open source protocol. Lati ni imo pupo lori Sputnik e lo si ori eka yi http://https://sputnik.fund/ ati lori http://https://gov.near.org/tag/sputnikdao

Follow us for more on

Website: https://near.org/
Twitter: https://twitter.com/NearprotocolNG
Telegram Official Channel: https://t.me/cryptonear
Telegram Nigeria Community Chat: https://t.me/NPKGUILD

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet