Isiwo dada ni awujo pelu NEAR: Eyi to mu igbalode wa si eto crypto.

Ni gbogbo imo to awon nkan ti n lo daradara ni a ti ri eto eyi pada ninu ero technology ti o si ti di nkan amuyan gan ni awujo papa ni inu odun 2022. Pelu bi awon eka oja crypto ti n gba ode kan papa ni eto ijo (ESG) ti won gba NEAR wa so inu Web3 world.

Bi CEO ESG fund shey n $500B ni odun 2021 ni ori ero oro aje, ti eto oro aje shey n lo si ninu ero eto crypto ti igba lode ti o si n lo ninu eto. Ni owolowo yi Bitgo je oga ninu eto on-chain Bitcoin ti won shey eya gbigbin Bitcoin bi pectin Mejila ni Kaka ki ri agbaye pelu bi egberun marun token ti NEAR tokini Hershey dara po mo won. Eto NEAR protocol ni igbagbo pupo ninu Bitgo ti o wun ni anfani lati le wo inu ecosystem wan lo lati gba eya awon eto oro aje won lati ma lo Bitgo fun isho owo wan.

Gbogbo awon eto oro aje Bitgo kaka kiri agbaye papa awon oni ero cryptocurrency ni gbogbo agbaye ati awon oni ero bi egberun mega ju belo. Ti awon eto oro aje bi Goldman Sachs, Craft Ventures, Digital Currency Group, DRW, Galaxy Digital Ventures, Redpoint Ventures ati Valor Equity Partners ti Bitgo je oga ni inu eto ero igbalode ti won pese iso, idawo, idabobo, ati eto liquidity fun awon era won.

Mi Mi Si Inu Eto Ero Blockchain

Bi awon ero ori Ita get shey gbe eto wa ni 2021 larin awon eyan to wa ni Nigeria, Cameroon ati Canada ninu eto Foundation kan, eyi to bere gegebi DAO recordi ati NxM guild ti won si gba eto to dara ni ara won ti an pe ni “imu ni na owo ni arin awujo” .

Lati gba owo ni arin awon NFT bi C1 ti won mu ero “ti o ma n mu owo wa fun awon eyan ti awon ti won o ba ni anfani si eto blockchain ati NFT”. Awon iru eto ti C1 mu wa si awon awujo ni agbara gan bi ki wan shey eto record labeli ati aye fun awon ti wo o ni access si irin ishey igbalode C1.

Ni ori ero NEAR, awon orisirisi projecti lo wa ti wan gbimopo lati dekun ijamba climate bi SISU, SISU je eka ti won je eto DAO ti won ma support awon eto ninu ki a ma fi owo us Web3 ti wan je DAO ti o n shey ise fun climate, won fun awon eyan ni anfani lati ma ko pa ninu eto initiative yi. SISU ma n fun awon eyan ni supporti to pe ye lae si idiwo kankan Iri eyelid je bi Siera Nevada ti won iri awon project yi ma ni anfani to po lori won ma n lo NFT ati ikan igbin fun anfani won.

NEAR Protocol ni iwulo po peye ninu eto e ti wan commit ara wan si ki won ma fun awon eyan ni certificate climate neutral in odun 2021, Foundation yi enclose South pole, flick climate ati footprint, ni by egberun ogbon ton ni CO2 ti o je Foundation fun eka NEAR.

Also put for more information visit Near.org,

Twitter of NEAR Nigeria https://twitter.com/NearprotocolNG?t=1tQLCyGGy4XsVKk7nAzkwA&s=09

Telegram of NEAR Nigeria t.me/NPKGUILD

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM