IWULO APONLE TI AN PE NI DAO SI AWON EYAN EYA ILO NIGIRIA

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
4 min readJul 10, 2022

--

Ni akoko ti awa yi a ni eto ero ti an pe ni blockchain ati web3.0 ti o ti gbo de kan ti a de ni nkan ti an pe ni DAO (Decentralized Autonomous Organisation) awon DAO ti an so yi wo o ki n shey tuntun wo n ti wa ni ojo to ti pe bi odun 2016 ti DAO akoko wa ni ida sile lati owo eto ero ti an pe ni Ethereum blockchain ti wo si ni bi owo ori crowdfunding bi ogun ogabon million (150 million dollasi) eleyi je projecti to gbode kan.

DAO (Decentralized autonomous Organisation) bi oruko e shey lo je ero eto organisationu ti o je ero ti an pe ni decentralization ati eto democrazy ti igba oni. E je ki a wo innkan ti an pe DAO ti o wa lati owo Hassan ati De Filippi ni 2021 ti o je ti ode o ni.

“ Inkan ti an pe ni DAO je owun elo ninu ero blockchain systemu ki o je ki awon eyan ko ara won po lati jo jiroro pelu ara won ninu ero eto blockchain ni agbaye ti o si wa decentralized pelu”

O wun to dun moni nonu DAO yi ni win pe awon elo re ni an fanni lati jo jiroro tabi di ibo fun eka to ba wun won eyi ti an pe ni dicision making ni ede gesi. Oju shey awon DAO yi ko wa lati owo awon eyan sugbon o wa lori ero codi ti o dara, codi yi deni awon olo DAO jaduro lelori awon ilana ati ishey DAO yi wa ni ori blockchain agbaye lori ise Ledger ti gbogbo nkan to ba n shele lori DAO na ma wa ni imulowole.

Awon Elo DAO Ati Ishey Won

Opolopo ona lowa ti a le fi shey eto DAO

▪️Ti Eyan ba ti ni tokini ti o ni idanimo inu DAO lowo, awon tokini yi ni o ma fun awon eyan ni anfani lati le di omo egbe inu DAO yi ki won ke ni anfani lati le ma dipo tabi yan nini euti DAO. Awon DAO mi wan fun awon omo egbe won ni anfani lati le Jo sowo po dibo fun tokini yo ba ye ti awon DAO imiran si ma n fun awon egbe lotobi tokini to ba poju ni anfani lati le ma sowopo dipo. Ni gbogbo e gbogbo e orisirisi DAO lo ni ilana won ninu bi awon omo egbe she le dipo tabi mu ipinu won wa si imushe.

▪️Awon ti won da lori ipinu

▪️Awon ti won da lori bi eyan ba shey gbajumo si

▪️A de tuni eyi ti an pe ni DAO ajoshe ti ede gesi n peni communiti DAO

Awon DAO yi shey ise lori codi ati nkan ti oyinbo n peni smart contract ti awon codi yi si wa ni shishile fun awon ara ilu, smart contracti yi je ki awon codi yen je ni lilo ati lori ijoba to da lelori.

Iwulo Ero Eto DAO

▫️Alelo DAO yi ni ori ishey ijoba tabi ishey ololo ti ere e ati loss e ma n je pinpin lari awon ti won jo ni DAO na

▫️ Alelo awon DAO yi fun nkan ti an pe ni charity ni ede gesi, eyi to wa ni ori ero eto NEAR blockchain wa ni iwulo ni inu ijamba to shele ni ori lede Ukraine.

▫️Alelo fi ra owun ti an pe ni non-fungible tokini

▫️ Atunle lo lati ma fi wun awon eyan ni owo tabi owun a ni moni.

Awon DAO ti a tin so yi won o le wa ki won ma ni ibiti wan kusi, ti a ba wo DAO to koko wa ni ise ni odun 2016 ti Ethereum da sile won hacki e lori bug cody ti won si shey ijanbanu owo bi gbon million(50 million dollasi) sugbon hacki pada wa nullified bi awon ede gesi shey ma n pe lori fork nini Ethereum blockchain. Eleyi lo je koko inu DAO ti o a secure lori blockchain ti ko de le ni ijamba.

Bi NEAR protocol shey je ero eto to yarabi asa ti o wa ni ori scalable layer akoko ni inu blockchain, o je nka ti eyan le shey ishey lori.

A ni nkan ti oyinbo n pe ni Sputnik DAO ati Astro DAO lori NEAR protocol to awon eyan le ko DAO ti won lelori ni iran run. Ni ori Astro DAO eyan leri ika se bi mewa isheju ti eyan ma fi launchi ero eto DAO e lelori.

A ko eto NEAR protocol Nigeria(NPK) guild lori eyi to wa ni ita lowolowo yi ti an pe ni Astro DAO ti o wa ni ori ipele lati ma fin gba awon eyan si lori.

Ni akojopo

Eto ero DAO a ma funi ni anfani lati shey ipinu lori awon governance ati eya imuduro. Awon olu lo DAO ti di popu ni awujo to ode oni o si je nka to dara gan.

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet