Kini An Peni Ise Apinfunni NEAR Ni Eto Ojo Ola

--

Enle eyin ara ile shey alafia ni a bayi n oo. Atun ti de bi a shey ma n de, ona otun ni a mu wa yi.

Bi a shey mo wi n pe ero eto crypto ti lo le ni bi igba kan ri ni odun 2018/2019 shugbon ko ri bi eleyi shey ri yi. Ti Odun yi lole pupo ti awon eyan si mo ni ara. Ero eto crypto o gbonoo si iru ishele yi ni odun meta se yi n shugbon awon o lu lo ero crypto ni wan je ko gbona ni ara. Orisirisi projecti ni oun wa ninu eka yi, awon ti won gbona gan ti wo n si mo oun ti wo n shey.

Ero NEAR foundationu a ma gba a doju ko oun to ni lati shey ni pepe pelu awon eto ecosystem ti o wa ninu re. Wo so wi n pe ijakulo to wa ni inu eto NEAR lowo yi ko di n ero eto ti n oun lo lowo ni inu eto NEAR, koda wo n ni akoko yi gan lo daraju ti oun melomelo ma ma sheyle ni inu eto na. Ki eto to daraju lo le ma waye ni inu eto NEAR, wo no awon igbese pataki ti wo n fe gbe ni arin yi ko eto na le jade dada ti oja ba ti dara pada. Awon eto na ni a ka kale yi.

Eto Apinfuni Ninu Ero Eto Near Foundationu

Apinle eto NEAR foundationu ni ki awon ero wan ni eto lati ma fi jeki awon community ni anfani lati ma gbe ise tabi aworan won sinu eti ero Near, eleyi je ona lati le ma fi jeki awon youtu ri ise tabi fi talent won wo n.

Apinle ero eto NEAR foundationu je ipinle to wa decentralized bi awon oyinbo shey n pe,o je a ponle eto decentral ecosystem. NEAR ma gbimo si eto eka ecosystem lati fi le gbe owo to dara duro. Wo ni igbinmo to ma sa aye derun fun awon eka to n lo wo n.

Wo no eto lati gbe operationu to ro ru n sile fun awon ti wo n lowo ati awon awujo wan. Wo ni eto lati shey ise to dara fun awon communiti won lati ko gbogbo igbinmo si oju kan. Ki ko eka producti ati enginir si abe awon og ti an pe ni product ati eniginir ti o ma fu wan ni anfani lati mo koko eto websiti won (eleyi to je koko eka inu NEAR ecosystemu) sugbon o ni eka si era ti awon oloyibo n pe ni ipinle technical ati awon oni ba ra e. Lati ni iro eyi a ti da ise to lo bi merinla din ni merin, ti a le ri ni inu apele to wa ni isale yi.

Ni pelu eto ti wo n gbe kale yi awon metadin login awon eyan ma wa fi eri NEAR foundationu sile, wo ma ma lo iro wo ni inu eto NEAR ecosystemu fun rara e eleyi ni o ma fun won ni anfani lati darapo mo awon to n lo bi igbamefa ati ju belo lati ma ko awon projecti do dara si inu NEAR. Awon miran ma ma dara po mo NEAR hub ti o je olori communiti won, ri ri awon ore ati ara fi ise sile tabi lo si inu teamu miran ma n ko irewesi okan ba eyan. Inu wa dun si ise takun takun ti wan shey lati fi gbe ero NEAR si ibute ojo to dara.

Eleyi kin shey ijanukule sugbon ona ara to dara ju lo lati file shey ise pelu ecosystem NEAR ni, inu wo n si dun si awon osise wan. Wo ni o ti fi wan wi n pe ise takun takun ni awon n shey be wan si ti gbaradi fun eto ero bear to n bo lo na.

Inu wa dun dada lori ishey a shey yanju ti a ti shey seyin a de ni igboya wi n pe ise to n bo loan ma dara ju ti ati eyin walo.

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet