NEAR gbimopo pelu ero Google Cloud lati le gbe itesiwaju Web3 soke

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
3 min readOct 16, 2022

Idunu ati ayo ni NEAR Foundation shey fi iroyin amuowopo pelu Google Cloud ati NEAR Protocol si araye. Ni ilosiwaju, Google Cloud lo ma fun awon eto NEAR ni irin shey abo to peye. Pulu eto to gba gbogbo eyan, Google Cloud ma fun awon ti wan ko eto NEAR ni abo ati iso to peye.

Iroyin nla ni eleyi je fun gbogbo awon ti won ba n ko ile si ori eto NEAR, tori isowopo yi ma mu iyato ba eto Web3 ati blockchain ni apapo ti o ma mu awon ikole lati le shey ise to dara ati lati le je ki kiko awon eyan bi won shey ma n kole ko dara.

“Pelu inu dundun ati ayo ni a fi mo isowopo yi ko wa si aye, biba eto to mo nipe irin ise Web3 sowopo je nkan ara lori internet bi gbogbo wa shey mo.” a gbo oro yi wa lati enu Marieke Flanent, CEO fun NEAR Foundation. “Irowopo yi ma je ki awon nkan ara tu n shuyo lori eto NEAR Protocol lati le fun awon generation ti o n bo ni iranwo ati abo ito ni si ona to peye lati le ma tesiwaju ni kiko ile ni ori ero NEAR Protocol.”

Fi fi idabobo awon ikole NEAR pelu Google Cloud

Ni inu odun to kojalo, NEAR ti rin lo si waju irin shey won to yara bi asa, ti o ni igboja lati gba eto soke ati to ni iso abobo to peye. Ni akoko yi bi Ogun millionu accounti (20 million accounts) titi di asiko yi bi Ogun Ogbon millionu transactionu (200 million transaction) ati bi Ogbo Ogoji ati Ogbo Meridinlogboji transactionu ni owa ni ori ero NEAR. Ki ko ile si ori NEARCON ni odun 2022, ti o fi ise akiki yon ti NEAR protocol nshey ni ti bi Merindilogun projecti ti n ko ile si ori ero NEAR Protocol.

Bawo ni awon bi Ogun projecti to n ko ile si ori NEAR shey ma je anfani isowopo pelu Google Cloud

Google Cloud ma shey eto to munoduro fun NEAR Remote Procedure Call (RPC) ti node provider fun Pagoda eto fun gbogbo ise Web3. Eleyi ma fun awon developasi ni aye lati le dipiloyi awon codi ni kia kia, awon eto Pagoda ma n ba awon developesi le ko codu ti dara pelu won iwe ti won ti ko sile fun awon developesi to ba fe ko ile si ori NEAR, eyi ma fun won ni anfanni lati le lo iwe yi pelu iranrun ati lati le to won si ona.

“A ma fun awon eto NEAR ni gbogbo iso ati abo ti won ba nilu lati le gba eto Protocol na si iwaju.” a gba ori yi wa lati enu Carlos Arena, Director fun eto ero ise fun Google Cloud. “A ma tun bo fun awon eto to dara ni idabobo to peye lati le ma tesiwaju lati le gba asa blockchain technologi si iwaju fun iwulo gbogbo awon ara awujo ni irowo rose ati ni shi shey n tele.

For more information, follow us at;

Twitter :https://twitter.com/nearprotocolng?s=21

Telegram: https://t.me/NPKGUILD

website: https://nearnigeria.org/

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM