NI IMOJUTO NEAR: ETO GBIGBA REO OLUYA NFT SI ETO AMULU TI IGBALODE

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
3 min readJun 24, 2022

--

Ni igba ti Matt Aaron ri iya to awon eyan kosi lilo NFT lori ero Near protocol, o tu n ri aye to wa ni inu oja ori ero to o ni blockchain e. Ero to Matt ni si eto yi ni lati shey ile ifi owo si NEAR bi apeere ero ti o da sile lati tracki irin se Ethereum. Leyin ti won ba ti launch ni ose yi, NEAR tracker shi je ise ti on wa ni le ti ama be re si ni shey sugbon Mark so win pe “oje Amunudun lati sheshe bere” .

“Gegebi eni to mo nipa blockchain to fe so Itan lori nkan to n shele nibe a ma ni lati fi eto Layer akoko yato si ti ero Ethereum ti a ro boya awon eyan wa ma le tracki. “

“ An ri gbogbo iran lowo ta ni lati fi bere ise na,” ni a fikun awon ero to ma ninu community ati iran lowo 4NTS lati fi connect pelu ero NEAR protocol ati lati gbede ebute ayo. Lati ko eto ero Web3 o yato si ero eto Web2. Kini idi eyi? Idi ni pe ero eto Web3 wa decentralized ju Web2 lo ati win pe won ma ni anfani si awon oya won, eleyi wa ni owo eni to ni oluya lati gbe iya e de oke.

Anfanni to wa ninu communiti ni eto ero web3 ni inu awujo wa yi

Matt so winpe “Ki projecti kan to le wa ni iyege awon to n shey ise ninu agbemo yen gbodo wa ni ifowosowopo ati ni isho kan. Won gbodo ma she anfani fun awon to ba sheyshey wa si inu communiti na eyi lo ma mu iso wo po fun gbogbo awujo.” Awon to wa ninu ishwo NEAR protocol ma n gba alejo wole won si tun ma fi ona won alejo, eleyi ni an pe ni Web 2. Ni inu Web3 awon eyan ni wan ma wa ona fun a ra won kosi eni to ma to wan si ona bi apeere DAO ati Tokini ijoba.

Bi a shey ko ero NEAR si ori ero blockchain fun awon awujo

Jordan Gray to wa ni inu DAO ti an pe ni Tenk to awon igbinmo NEAR launchi si ori ero to an pe ni Misfits NFT so win pe “ ki ko igbemo si ori NEAR ni o daraju ni papa fun awon to ba fe yi lati ero Web2 si Web3 bi apeere eto ero ifi owo si NEAR to ri wi n pe bibere pelu e dara ju ki eyan bere pelu awon ifi owo si bi Metamask, Trustwallet ati bebelo eleyi ni o fun Jordan ni anfani lati ko eto si ori ero NEAR.

Oludasile Naksh Sdi Lakshmi so wi n pe awon oluwa NEAR shey ise to dara gan lori didn’t ero NEAR kale ni paapa lori iwo ifi owo pamo si won eleyi ti mo ni fe si, mo si tunti lo awon eyan mi bi won shey ma n shey ile ifi owo si yi pelu gbogbo awon aditi ati awon ton gboran. Awon ti won ma build si ori NEAR je awon ti wo ni opolo gan.

Kini agbara wan eyan to wa ninu communiti yi ni igba ti oja o ba da

Alejandro Betancourt oludasile NEAR Misfits ti o da so win pe bi ero NEAR shey ma n wa ni igbati oja ba wa le ja sile di e awon eyan inu communiti ma n fi arable ni. Awon ti won ko eya lori NEAR ma n fi arabale ni ati win pe NEAR ti wa ni awujo lati odun 2020 ti o si tun gbera si ninu oja to wale. NEAR je eto to dara pupo ni awujo to ti awon eyan ni fesi a o dara pupo ti awon eyan ma n wa ra coin e.

--

--

Near Protocol Nigeria (NPK Guild)
Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

Written by Near Protocol Nigeria (NPK Guild)

NPK Guild is a Near Protocol Community based in Nigeria, aimed at educating and incentivising young Nigerians onBlockchain technology and the NEAR ECOSYSTEM

No responses yet